2 Kíróníkà 29:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ohun ìyà sí mímọ́ sì jẹ́ ẹgbẹ̀ta màlúù, àti ẹgbẹ̀ẹ́dógún àgùntàn.

2 Kíróníkà 29

2 Kíróníkà 29:23-36