2 Kíróníkà 29:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Hésékíà sì pa á láṣẹ láti rú ẹbọ sísun lórí pẹpẹ, bí ẹbọ sísun náà ti bẹ̀rẹ̀, orin sí Olúwa bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ìpè àti pẹ̀lú ohun èlò orin Dáfídì ọba Ísírẹ́lì.

2 Kíróníkà 29

2 Kíróníkà 29:24-33