2 Kíróníkà 29:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní kùtùkùtù òwúrọ̀ ọjọ́ kejì, ọba Hésékíà sì kó olórí àwọn ìjòyè jọ, ó sì lọ sókè ilé Olúwa.

2 Kíróníkà 29

2 Kíróníkà 29:17-21