2 Kíróníkà 28:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìyòókù iṣẹ́ ìjọba rẹ̀ àti gbogbo ọ̀nà rẹ̀, láti ìbẹ̀rẹ̀ títí dé òpin, ni a kọ sínú ìwé àwọn ọba Júdà àti ti Ísírẹ́lì.

2 Kíróníkà 28

2 Kíróníkà 28:19-27