2 Kíróníkà 28:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Áhásì mú díẹ̀ nínú ìní ilé Olúwa àti láti ilé ọba àti láti ọ̀dọ̀ ọba ó sì fi wọ́n fún ọba Ásíríà: ṣùgbọ́n èyí kò ràn wọ́n lọ́wọ́.

2 Kíróníkà 28

2 Kíróníkà 28:14-24