2 Kíróníkà 28:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Áhásì sì jẹ́ ẹni ogún ọdún (20) nígbà tí ó bẹ̀rẹ̀ ìjọba, ó sì jẹ ọba ní Jérúsálẹ́mù fún ọdún mẹ́rìndínlógún (16). Gẹ́gẹ́ bí i Dáfídì bàbá rẹ̀ kò sì ṣe ohun rere ní ojú Olúwa.

2 Kíróníkà 28

2 Kíróníkà 28:1-9