2 Kíróníkà 27:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìyòókù iṣẹ́ ìjọba Jótamù, pẹ̀lú gbogbo àwọn ogun rẹ̀ pẹ̀lú ohun mìíràn tí ó ṣe, ni a kọ sínú ìwé àwọn ọba Ísírẹ́lì àti ti Júdà.

2 Kíróníkà 27

2 Kíróníkà 27:1-9