2 Kíróníkà 26:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ùsáyà sì kọ́ ìlú sí Jérúsálẹ́mù níbi ẹnu bodè igun, àti nibi ẹnu bodè àfonífojì àti nibi ìṣẹ́po-odi ó sì mú wọn le

2 Kíróníkà 26

2 Kíróníkà 26:1-16