2 Kíróníkà 26:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba Ùsíá sì ní ẹ̀tẹ̀ títí di ọjọ́ ikú rẹ̀. Ó sì gbé ní ilé ọ̀tọ̀ adẹ́tẹ̀, a sì ké e kúrò ní ile Olúwa. Jótamù ọmọ rẹ̀ sì gba ipò rẹ̀, ó sì ń ṣe ìdájọ́ lórí àwọn ènìyàn ilẹ̀ náà.

2 Kíróníkà 26

2 Kíróníkà 26:12-23