2 Kíróníkà 26:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sì takòó, wọn sì wí pé, “Kò dára fún ọ, Ùsáyà, láti sun tùràrí sí Olúwa. Èyi fún àwọn àlùfáà, àwọn ọmọ Árónì, ẹni tí ó ti yà sí mímọ́ láti sun tùràrí. Fi ibi mímọ́ sílẹ̀, nítorí tí ìwọ ti jẹ́ aláìsòótọ́, ìwọ kò sì ní jẹ́ ẹni ọlá láti ọ̀dọ̀ Olúwa Ọlọ́run.”

2 Kíróníkà 26

2 Kíróníkà 26:8-19