2 Kíróníkà 26:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ùsáyà sì pèsè ọ̀kọ̀, asà, akọ́rọ́, àti ohun èlò ìhámọ́ra ọrun títí dé òkúta kànnàkànnà fún ọwọ́ àwọn ọmọ ogun.

2 Kíróníkà 26

2 Kíróníkà 26:5-17