2 Kíróníkà 25:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àní, tí ẹ bá lọ jà pẹ̀lú ìmúláyàle ní ojú ogun, Ọlọ́run yóò bì ọ́ subú níwájú àwọn ọ̀tá, nítorí Olúwa ní agbára láti ràn ọ́ lọ́wọ́ àti láti bì ọ́ ṣubú.”

2 Kíróníkà 25

2 Kíróníkà 25:5-18