2 Kíróníkà 25:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fún ti iṣẹ́ mìíràn ti ìjọba Ámásíà láti ìbẹ̀rẹ̀ dé ìparí, ṣé a kò kọ wọ́n sínú ìwé àwọn ọba Júdà àti Ísírẹ́lì?

2 Kíróníkà 25

2 Kíróníkà 25:23-28