2 Kíróníkà 25:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní báyìí àwọn ọ̀wọ́ ogun tí Ámásíà ti rán lọ padà, tí wọn kò nípa nínú ogun gbógun sí àwọn ìlú Júdà láti Saaríà sí Bẹti-Hórónì. Wọ́n pa ẹgbẹ̀rún mẹ́ta nínú wọn, wọ́n sì kó ọ̀pọ̀ ìkógun ńlá.

2 Kíróníkà 25

2 Kíróníkà 25:4-14