2 Kíróníkà 24:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nípasẹ̀ ọba, a ṣe àpótí wọ́n sì gbé e sí ìta, ní ẹnu ọ̀nà ilé Olúwa.

2 Kíróníkà 24

2 Kíróníkà 24:1-9