2 Kíróníkà 23:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó mú gbogbo àwọn ọkùnrin wà ní ipò ìdúró pẹ̀lú ohun ìjà rẹ̀ ní ọwọ́ rẹ̀, yí ọba ká ní ẹ̀bá pẹpẹ àti ilé Olúwa láti ìhà gúsù sí ìhà àríwa ilé Olúwa.

2 Kíróníkà 23

2 Kíróníkà 23:2-19