2 Kíróníkà 20:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìbẹ̀rù Ọlọ́run wá si orí gbogbo ìjọba ilẹ̀ náà nígbà tí wọ́n gbọ́ bí Olúwa ti bá àwọn ọ̀ta Ísírẹ́lì jà.

2 Kíróníkà 20

2 Kíróníkà 20:19-31