2 Kíróníkà 20:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jóhóṣáfátì tẹ orí rẹ̀ ba sílẹ̀ pẹ̀lú ojú rẹ̀, àti gbogbo àwọn ènìyàn Júdà àti Jérúsálẹ́mù wólẹ̀ níwájú láti sin Olúwa.

2 Kíróníkà 20

2 Kíróníkà 20:15-28