2 Kíróníkà 2:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Hírámì fi kún un pe:“Ìyìn ni fún Olúwa, Ọlọ́run Ísírẹ́lì, tí ó dá ọ̀run òun ayé! O ti fún ọba Dáfídì ní ọmọ tí ó gbọ́n, tí ó kún fún ìmọ̀ àti àkíyèsí, tí yóò kọ́ ilé fún Olúwa àti ààfin fún ara rẹ̀.

2 Kíróníkà 2

2 Kíróníkà 2:8-18