2 Kíróníkà 19:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jéhóṣáfátì sì ń gbé ní Jérúsálẹ́mù ó sì jáde lọ padà láàárin àwọn ènìyàn láti Béríṣébà dé òkè ìlú Éfúráímù, ó sì mú wọn padà sọ́dọ̀ Olúwa Ọlọ́run baba wọn.

2 Kíróníkà 19

2 Kíróníkà 19:1-5