2 Kíróníkà 19:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jéhù aríran, ọmọ Hánánì jáde lọ láti lọ pàdé rẹ̀, ó sì wí fún ọba pé, “Sé ìwọ yóò máa ran ènìyàn búburú lọ́wọ́, kí o sì fẹ́ràn àwọn tí ó kórìíra Olúwa? Nítorí èyí, ìbínú Olúwa wà lórí wa.

2 Kíróníkà 19

2 Kíróníkà 19:1-5