2 Kíróníkà 18:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ìparí, ni ẹ̀mí kan wá ṣíwájú, ó dúró níwájú Olúwa ó sì wí pé, ‘Èmi yóò tàn án.’“ ‘Nípa ọ̀nà wo?’ Olúwa beèrè.

2 Kíróníkà 18

2 Kíróníkà 18:12-27