2 Kíróníkà 17:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọkàn rẹ̀ sì gbé sokè si ọ̀nà Olúwa, pẹ̀lúpẹ̀lù, ó sì mú ibi gíga wọn àti òrìṣà kúrò ní Júdà.

2 Kíróníkà 17

2 Kíróníkà 17:1-13