2 Kíróníkà 16:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwa kì í ṣe ará Etiópíà àti àwọn ará Líbíà àwọn alágbára ogun pẹ̀lu ọ̀pọ̀lọpọ̀ kẹ̀kẹ́ àti àwọn ẹlẹ́ṣin? Síbẹ̀ nígbà tí ìwọ bá gbẹ́kẹ̀lé Olúwa yóò sì fi wọ́n lé ọwọ́ rẹ.

2 Kíróníkà 16

2 Kíróníkà 16:1-14