2 Kíróníkà 16:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ásà sì bínú pẹ̀lú sí wòlíì nítorí èyí, ó sì mú un bínú gidigidi tí ó sì fi mú un sínú túbú. Ní àkókò náà Ásà sì ni díẹ̀ nínú àwọn ènìyàn náà lára.

2 Kíróníkà 16

2 Kíróníkà 16:8-14