2 Kíróníkà 14:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣérà ará Kúṣì yàn láti dojú kọ wọ́n, pẹ̀lú ọ̀pọ̀ ọmọ ogun pẹ̀lú ọgọ́rùn-ún mẹ́ta kẹ̀kẹ́, wọ́n sì wá láti jìnnà réré bí Máréṣà.

2 Kíróníkà 14

2 Kíróníkà 14:4-10