2 Kíróníkà 14:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó gbé àwọn pẹpẹ àjèjì kúrò àti àwọn ibi gíga. Ó fọ́ àwọn òkúta tí a yà sọ́tọ̀, ó sì gé àwọn òpó Áṣérà bolẹ̀.

2 Kíróníkà 14

2 Kíróníkà 14:1-8