2 Kíróníkà 14:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa lu àwọn ará Kúsì bolẹ̀ níwájú Ásà àti Júdà. Àwọn ará Kúsà sá lọ.

2 Kíróníkà 14

2 Kíróníkà 14:6-15