2 Kíróníkà 13:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ènìyàn lásán aláìwúlò péjọ yí i ká, wọ́n sì kẹ̀yìn sí Réhóbóámù ọmọ Sólomónì ní ìgbà tí ó sì kéré tí kò lè pinnu fún ra rẹ̀, tí kò lágbára tó láti takò wọ́n.

2 Kíróníkà 13

2 Kíróníkà 13:1-13