2 Kíróníkà 13:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣé ẹ̀yin kò mọ̀ pé Olúwa Ọlọ́run fún Dáfídì àti àwọn àtẹ̀lé rẹ̀ ni oyè ọba títí láé nípasẹ̀ májẹ̀mú iyọ̀?

2 Kíróníkà 13

2 Kíróníkà 13:1-13