2 Kíróníkà 12:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Réhóbóámù sinmi sínú ìlú ńlá ti Dáfídì. Ábíjà ọmọ rẹ̀ sì rọ́pò rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọba.

2 Kíróníkà 12

2 Kíróníkà 12:8-16