2 Kíróníkà 11:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Réhóbóámù fẹ́ràn Mákà ọmọbìnrin Ábúsálómù ju èyí kejì nínú àwọn ìyàwó rẹ̀ àti àwọn àlè rẹ̀ lọ. Ní gbogbo rẹ̀, ó ní ìyàwó méjìdínlógún àti ọgọ́ta àlè ọmọkùnrin méjìdínlọ́gbọ̀n àti ọgọ́ta ọmọbìnrin.

2 Kíróníkà 11

2 Kíróníkà 11:19-23