2 Kíróníkà 11:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Réhóbóámù fẹ́ Máhálátì tí ó jẹ́ ọmọbìnrin ọmọkùnrin Dáfídì Jérímótì àti ti Ábíháílì, ọmọbìnrin ọmọkùnrin ti Jésè Élíábì.

2 Kíróníkà 11

2 Kíróníkà 11:15-23