2 Kíróníkà 11:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn àlùfáà àti àwọn ará Léfì, láti gbogbo ẹ̀yà wọn jákè jádò Ísírẹ́lì wà ní ẹ̀bá rẹ̀.

2 Kíróníkà 11

2 Kíróníkà 11:4-17