2 Kíróníkà 10:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Réhóbóámù sì lọ sí Ṣékémù nítorí gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ti lọ síbẹ̀ láti fi jẹ ọba.

2 Kíróníkà 10

2 Kíróníkà 10:1-8