2 Kíróníkà 1:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ọba náà ṣe fàdákà àti wúrà gẹ́gẹ́ bí ó ti wọ́pọ̀ ní Jérúsálẹ́mù bí òkúta, àti Kédárì ó pọ̀ bí igi Síkámórè ní àwọn ẹsẹ̀ òkè.

2 Kíróníkà 1

2 Kíróníkà 1:8-16