2 Jòhánù 1:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí sì ni ìfẹ́, pé, kí àwa máa rin nípa òfin rẹ̀, èyí ni òfin náà, àní bí ẹ ti gbọ́ ni àtètèkọ́ṣe, pé, kí ẹ̀yin rìn nínú rẹ̀.

2 Jòhánù 1

2 Jòhánù 1:1-12