2 Jòhánù 1:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Oore-ọ̀fẹ́, àánú, àti àlààáfíà, láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Baba, àti láti ọ̀dọ̀ Jésù Kírísítì, Ọmọ Baba, yóò wà pẹ̀lú nínú òtítọ́ àti nínú ìfẹ́.

2 Jòhánù 1

2 Jòhánù 1:2-7