1 Tímótíù 6:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tìmótíù, máa sọ ohun tí a fi sí ìtọ́jú rẹ, yà kúrò nínú ọ̀rọ̀ asán àti ìjiyàn ohun tí a ń fi èké pè ni ìmọ̀;

1 Tímótíù 6

1 Tímótíù 6:10-21