1 Tímótíù 5:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ma ṣe máa mu omi nìkan, ṣùgbọ́n máa lo wáìnì díẹ̀ nítorí inú rẹ, àti nítorí àìlera ìgbàkúùgbà.

1 Tímótíù 5

1 Tímótíù 5:16-24