1 Tímótíù 4:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Má a fiyèsí nǹkan wọ̀nyí; fi ara rẹ fún wọn pátápátá; kí ìlọṣíwájú rẹ lè hàn gbangba fún gbogbo ènìyàn.

1 Tímótíù 4

1 Tímótíù 4:9-16