1 Tímótíù 4:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Má ṣe jẹ́ kí ẹnikẹ́ni gan èrè rẹ; ṣùgbọ́n kì ìwọ jẹ́ àpẹẹrẹ fún àwọn tí ó gbàgbọ́, nínú ọ̀rọ̀, nínú ìwàhíhù, nínú ìfẹ́, nínú ẹ̀mí, nínú ìgbàgbọ́, nínú ìwà mímọ́,

1 Tímótíù 4

1 Tímótíù 4:8-16