1 Tímótíù 4:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

NÍṢÍNṢIN YÌÍ, èmi ń tẹnumọ́ ọ́ pé ní ìgbà ìkẹyìn àwọn mìíràn yóò kúrò nínú ìgbàgbọ́, wọn yóò máa fiyèsí àwọn ẹ̀mí tí ń tannijẹ, àti ẹ̀kọ́ àwọn ẹ̀mí èsù.

1 Tímótíù 4

1 Tímótíù 4:1-7