1 Tímótíù 2:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo fẹ́ kí àwọn ọkùnrin máa gbàdúrà níbi gbogbo, kí wọ́n máa gbé ọwọ́ mímọ́ sókè, ní àìbínú àti àìjiyàn.

1 Tímótíù 2

1 Tímótíù 2:5-9