1 Tímótíù 2:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹni ti ó fi ara rẹ̀ ṣe ìràpadà fún gbogbo ènìyàn—ẹ̀rí tí a fi fún ni ní àkókò tó yẹ.

1 Tímótíù 2

1 Tímótíù 2:3-8