1 Tímótíù 2:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ádámù kọ́ ni a tàn jẹ, ṣùgbọ́n obìnrin náà ni a tàn tí ó sì di ẹlẹ́ṣẹ̀.

1 Tímótíù 2

1 Tímótíù 2:4-15