1 Tímótíù 2:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí kò ṣe pẹ̀lú iṣẹ́ rere, èyí tí ó yẹ fún àwọn obìnrin tó jẹ́wọ́ pé wọ́n sin Ọlọ́run.

1 Tímótíù 2

1 Tímótíù 2:5-15