1 Tímótíù 1:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú àwọn ẹni tí Híménéù àti Alẹkisáńdérù wà; àwọn tí mo ti fi lé Sàtánì lọ́wọ́, kí a lè kọ́ wọn kí wọn má sọ̀rọ̀-òdì mọ́.

1 Tímótíù 1

1 Tímótíù 1:18-20