1 Tímótíù 1:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

fún àwọn àgbèrè, fún àwọn aláyídà, fún àwọn onísòwò-ẹrú, fún àwọn èké, fún àwọn abúra èké, àti bí ohun mìíràn bá wà tí ó lòdì sí ẹ̀kọ́ tí ó yè kooro.

1 Tímótíù 1

1 Tímótíù 1:9-18