1 Tẹsalóníkà 5:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ bu ọlá fún wọn gidigidi nínú ìfẹ́, nítorí iṣẹ́ wọn. Ẹ sì máa wà ni àlàáfíà láàrin ara yín.

1 Tẹsalóníkà 5

1 Tẹsalóníkà 5:11-19